Olùbẹ̀rẹ̀

Megabyte

Ẹ̀kàlẹ́gbẹ̀

Wọlé láti fi pamọ́

Ìtúmọ̀ Yorùbá

Nǹkan bí mílíọ̀nù ẹkajọ nínú ìpamọ́ olóǹkà.

Ìtúmọ̀ Gẹ̀ẹ́sì

About one million bytes of digital storage.

Àpẹẹrẹ Yorùbá

Àwòrán tí a fún kù lè jẹ́ ẹ̀kàlẹ́gbẹ̀ kan tàbí méjì.

Àpẹẹrẹ Gẹ̀ẹ́sì

A compressed photo can be one or two megabytes.

Àwọn ọ̀rọ̀ tó jọra

Àwọn ọ̀rọ̀ mìíràn nínú Dátà