Olùbẹ̀rẹ̀

Compute

Fẹ̀rọsírò

Wọlé láti fi pamọ́

Ìtúmọ̀ Yorùbá

Ṣíṣe ìṣirò tàbí ìṣàmúlò dátà pẹ̀lú ẹ̀rọ.

Ìtúmọ̀ Gẹ̀ẹ́sì

To perform calculations or process data with a machine.

Àpẹẹrẹ Yorùbá

Iṣẹ́ ìsọ̀rọ̀-siópó ń fẹ̀rọsírò ìpele èsì ìwádìí.

Àpẹẹrẹ Gẹ̀ẹ́sì

Cloud services compute rankings for search results.

Àwọn ọ̀rọ̀ tó jọra

Àwọn ọ̀rọ̀ mìíràn tí a fọwọ́sí nínú Sọ́ftíwẹ̀