Àwọn bot ìfiránṣẹ́

Atúmọ̀ kan náà pẹ̀lú ojú òpó ayélujára. Fi ọ̀rọ̀ tech sí i ní Gẹ̀ẹ́sì tàbí Yorùbá kí o sì gba ìtumọ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.

  1. Yan app rẹ nísàlẹ̀ Tẹ app tí o ti ń lò nísàlẹ̀.
  2. Fi ọ̀rọ̀ tech ránṣẹ́ (àpẹẹrẹ cloud) Tẹ ọ̀rọ̀ tech kankan — tàbí fi àpẹẹrẹ tí a ti fi sílẹ̀ ránṣẹ́.
  3. Gba ìtumọ̀ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ Gbọ́ Yorùbá, ka ìtumọ̀, kí o sì rí àpẹẹrẹ.

Yan app rẹ

Àwọn ọ̀nà ń ṣí pẹ̀lú “HTML” tẹ́lẹ̀ lórí WhatsApp àti Telegram — tẹ send láti wá a.

WhatsApp

+2349073448062

Ó ń ṣí pẹ̀lú àpẹẹrẹ rẹ tẹ́lẹ̀ — tẹ send.

Ṣí WhatsApp

Messenger

@atumotech

Ṣí chat kí o sì tẹ ọ̀rọ̀ tech kankan.

Ṣí Messenger

Instagram

@atumotech

Ṣí DM kí o sì tẹ ọ̀rọ̀ tech kankan.

Ṣí Instagram

Àlàyé kíákíá

  • Fi help tàbí hi ránṣẹ́ nígbàkúgbà fún àṣẹ.
  • Dáhùn menu tàbí nọ́mbà 1–8 fún ọ̀rọ̀ ọjọ́, àwọn ẹ̀ka, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
  • Dáhùn 5 fún Gẹ̀ẹ́sì tàbí 4 fún Yorùbá.
  • Kò nílò àkọọ́lẹ̀ fún Atúmọ̀ Tech AI.

Àwọn ilé-ìwé àti ẹgbẹ́ le gba limit tó ga lórí WhatsApp: Ẹgbẹ́ lórí WhatsApp

Ṣe kíláàsì tàbí ìpàdé? Pe akẹ́kọ̀ọ́ láti dán àkójọ kannáà: Bẹ̀rẹ̀ kíláàsì